YouTube video

ASAKE - FUJI VIBE (LYRICS)

SO afrolyrics. ·

Press Play to watch on YouTube. Playback may vary by country and device.

About this video

@ASAKEMUSIC

@ASAKEMUSIC Fuji vibe lyrics video [Intro] Ololade mi Asake O ti po gan Gan, gan, gan Tune into the king of sound and blues [Verse 1] Ẹ ma f'agili ti wọ bọ o, kẹ ma fi were we mi Ẹni ba lọ lo le mọ, a bo le s'alaye ni Awọn ọmọ better ti pọ Keep your money tan ba n bọ Lokeloke la ma lọ Ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ Baby wa uhn uhn Mi o raye k'eeyan f'ẹran kan jeun Oje lo jẹ uhn uhn Ko n ṣe iwo nikan ẹgbẹ ẹgbẹrun [Chorus] Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju Ye, it's a mental O l'owo o lọ n loyun Ah sukerike rike, bumbum Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan Super extravagance l'ọmọ Emi l'Asake mẹdo ta n sọ Baby you catch my feelings ahn ahn I'm getting weaker You dey shack my head like gbana This your booty, are you from Ghana? Ọmọ olo make ka ma nawọ ya, ma se jẹ kan mọ This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ Ibadi yẹn fẹ ki n se wire into your aza Ọmọ olo mi, ye ma gaza (Gaza) [Verse 2] No pressure, wọn da mọ Ọga Ade ẹni lọ lo bọ Wọ America lọ fun tour Akata wọn pọlọpọ Plenty plenty ọmọge Wọn fẹ jẹ kin sa nile Ori mi lo yọ mi, ọta iba yọ mi Ọmọ ọpẹ I dey find my way Make bad belle no come stop my reign Bẹbẹ n lọ like a moving train Fun mi ni big big money no chicken change Owo n bọ, ọla n bọ, alaafia ati igbadun n bọ I no wan talk plenty talk, my record can back it up La-do-re-mi-fa-mi-so-la (L'Eko) Oluwa ni s'ọla Yarinya [Chorus] Haba! Vanessa, ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju Ye, it's a mental O l'owo o lọ n loyun Ah sukerike rike, bumbum Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan Super extravagance l'ọmọ Emi l'Asake mẹdo ta n sọ Baby you catch my feelings ahn ahn I'm getting weaker You dey shack my head like gbana This your booty, are you from Ghana? Ọmọ olo make ka ma nawọ ya, ma se jẹ kan mọ This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ Ibadi yẹn fẹ ki n se wire into your aza Ọmọ olo mi, ye ma gaza (Gaza) [Outro] Mr Money (Money dance) Money (Money dance) Money (Money dance) Money (Money dance)
Channel
SO afrolyrics.
Uploaded
9 August 2024
Duration
5 minutes 23 seconds
Source
YouTube